Ominira
Angélique Kidjo

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a


Onikaloukou wa n'fè ri ominira

Onikaloukou wa n'fè aseyori

Onikaloukou wa n'fè ri oyaya

Onikaloukou fèlo wa idaji

Mmm ewa ka lo


Ka lo fè wa tchitchè kori ominira

N'tori ominira toro ishè gan

Edahoun gbogbo yin foun ominira


Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira


Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a

Owa iya iyé é a


Onikaloukou wa n'fè ri ominira

Onikaloukou wa n'fè aséyori

Onikaloukou wa n'fè ri oyaya

Onikaloukou fèlo wa idaji


Ayé wa toro kawa ri ominira

Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan

Ayé sin wa lodo ominira

Mmm ewa ka lo


Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira


Onikaloukou wa n'fè ri ominira

Onikaloukou wa n'fè aséyori

Onikaloukou wa n'fè ri oyaya

Onikaloukou fèlo wa idaji


Ayé wa toro kawa ri ominira

Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan

Ayé sin wa lodo ominira

Mmm ewa ka lo a


Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira


Aaah ominira

Lo, ominira

Aaah ominira

Lo, ominira


Aaah ominira

Lo, ominira

Aaah ominira

Lo, ominira


Aaah ominira

Lo, ominira


Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man

Lo ominira


  Purchase "Ominira"   Purchase Entire Album   Email Video to Friends   Play Youtube "Ominira" Video   Play Spotify "Ominira" Song   View Wikipedia "Ominira" Entry   Receive Emails for Future Angélique Kidjo Lyrics

Email:

  Link to "Ominira"   Share on Facebook, Twitter, and more
  See Recommended Lyrics For You

Loading...

Lyrics by Angélique Kidjo

Related Songs